Telegram group: T.me/BBCNOUN [YOR213] Kín ni àṣà? tọ́kasí ọ̀nà ìgbé-ayé àwọn ìran èèyàn tàbí àwùjọ èèyàn kan [YOR213] Kín ni afọ̀? Ìró tí a fi ògidì èdè gbé kalẹ̀ [YOR213] Irúfẹ́ afọ̀ wo ni èyí: ‘ó dìgbà’ Ìkíni [YOR213] Orúkọ ọ̀jìnmì onímọ lìǹgúísíìkì tó dábàá àwọn èròjà tàbí fọ́nrán tó ń súyọ nínú afọ̀ ni: Roman Jakobson [YOR213] Ohun pàtàkì tí ẹ̀kọ́ tàbí kọ́ọ̀sì yìí (YOR 213) dálé ni – Àmúlò àti ìmọ̀-ọ́n-ṣe nípa èdè lílò [YOR213] Ta ni aṣafọ̀? Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ [YOR213] Kín ni èdè ewì? Èdè ajẹmọ́ lítírésọ̀ [YOR213] “Ìbánisọ̀rọ̀” gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ kan gbòógì kò túmọ̀ sí ọ̀kan nínú ìwọ̀nyí: Odì yíyàn [YOR213] Ọ̀kan nínú ìpèdè ìsàlẹ̀ wọ̀nyìí kì í ṣe afọ̀: Ẹkún sísun [YOR213] Kín ni èdè jẹ́? Ohun èlò pàtàkì fún ètò ìbánisọ̀rọ̀